Lyrics: Zlatan ft. Lil Kesh & Naira Marley – Jogor

0

Jogor Lyrics By Zlatan ft. Lil Kesh & Naira Marley

(INTRO)

DOWNLOAD MP3

==Y’all, Rexxie on this one==
Ah, ye, ji
E ni sun; ji; e ni sun
Ah; e ti mu imukumu mumumu mumukumu
Ahh, I can’t feel my leg; I can’t see myself
YAGI Level; oya

(HOOK- Zlatan)

I can’t see myself- I can’t see myself
I can’t feel my leg- I can’t feel my leg
Oju ti pade- oju ti pade
E jo, ta lo ma gbemi lole? Ta lo ma gbemi lole?

Ah; I can’t see myself- I can’t see myself
I can’t feel my legs- I can’t feel my legs
Oju ti pade- oju ti pade
E jo, ta lo ma gbemi lole? Ta lo ma gbemi lole?

(CHORUS)

Ah; mo ti Jogor- kuro n’be
Oju ti fe pade- ti fe pade
Ah, ese mi ti n ga nile se bi Mr Odunlade-
bi Mr Odunlade
Kuro n’be; mo ti Jogor- eh ehh
Oju ti fe pade- oju ti fe pade
Ahn; ese mi ti n ga nile se bi Mr Odunlade
Kuro n’be
Mo ti Jogor, oju ti pade; e jo, ta lo ma gbemi lole?
Kuro n’be; mo ti Jogor
ASe; o ju ti pade; e jo ta lo ma gbemi lole?

(VERSE 1- Lil Kesh)

Tan internet e, YAGI fe login
Ah; won ti po were po; won ti Jogor
Won ti mumukumu; won ti n F.uckk up
Won ti n w’omo t’o dun bi ifoko
K’e ma run je bi egungun bogo
Ah, a ti mu Brukutu, a ti mu Kaikai
FiLoud, we’ arizonal- laelae
A ti wa online on a faaji
A ti n ri everything on a 5-D
Ah, k’olomo gb’omo re, if not, ma f’omo re
Ma ko fun loloke, legbegbe, lonile
Ponran mi, gb’onrun e; ti n ba fi ko lu e
Wa daku bi eni kosi iwaju molue
Sister, won l’e like fore-play
O da; emi gan like, come play
Ma fo jagajaga, ma fo jakujaku
Ma tena wole kanle, san Shaku Shaku

(CHORUS)

kuro n’be
Oju ti fe pade- ti fe pade
Ah, ese mi ti n ga nile se bi Mr Odunlade-
bi Mr Odunlade
Kuro n’be; mo ti Jogor- eh ehh
Oju ti fe pade- oju ti fe pade
Ahn; ese mi ti n ga nile se bi Mr Odunlade
Kuro n’be

(Naira Marley- VERSE 2)

Ah, omo ase, o lo n pegbe mummy e ni sister
Wo, wa; omo pastor, believer
Iwo na ti lo n lale bi DiJa
Ah, alfa ni daddy e, Ruka
O ti n kegbe kegbe, o ti lo n fa shisha
Ahn, coke lo ma n mu tele
O ti lo n gbenu si baby oku
Ah, church ma lo dagbere Deborah
Ki lo n wa lo sona club?
Iwo nikan lo mo 57- eh eh
Iwo nikan lo mo Quilox- Quilox
Iwo nikan lo ma n wa ninu Benz, in the Toyota,
even gan Hilux
Ose dudu sa niwo fi gbowo
Wo church, se thanksgiving lodo Jesus
Lamba ti poju lenu e; nibo lo ti ma n ri?
ZLatan abeg no kill us

(CHORUS)

Ah, mo ti Jogor; kuro n’be
Oju ti fe pade- ti fe pade
Ah, ese mi ti n ga nile se bi Mr Odunlade-
bi Mr Odunlade
Kuro n’be; mo ti Jogor- eh ehh
Oju ti fe pade- oju ti fe pade
Ahn; ese mi ti n ga nile se bi Mr Odunlade
Kuro n’be

(VERSE 3- Zlatan)

Naira Marley is a go; Zlatan omo ibile is a go
Kuro n’be; mo ti fa were yo- fa were yo
I can’t see myself- I can’t see myself
Mo ma n jaye yi gan cos I can’t kill myself-
I can’t come and kill myself
Cigar no good but, o dan’pe loud is good for the health
[Loud is good for the what??]
Baby, don’t you trust me? Trust me, I don’t trust myself
Sister Linda- sister Linda
A n peyin nah- a n peyin nah
O gbe kini mi senu, o ni p’o taste bi Ribena
Me me Megwo- Megwo; arese jabata- arese jabata
Arapa regangan, Mr Jago ma pami nah- Jago ma pami nah

(CHORUS)

Mo ti Jogor; kuro n’be
Oju ti fe pade- ti fe pade
Ah, ese mi ti n ga nile se bi Mr Odunlade-
bi Mr Odunlade
Kuro n’be; mo ti Jogor- eh ehh
Oju ti fe pade- oju ti fe pade
Ahn; ese mi ti n ga nile se bi Mr Odunlade
Kuro n’be

(OUTRO)

Jogor; kuro n’be; oju ti pade
E jo ta lo ma gbemi lole?
Ase; mo ti Jogor; baba iya eee
Jogor; oju ti pade
E jo ta lo ma gbemi lole?
*Papa ejumare, mare jupako
==SpyritMix==

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here