Lyrics: Lord Of Ajasa Ft. Reminisce & Oladips – Pantiewa

0

PANTIEWA LYRICS BY LORD OF AJASA FT. REMINISCE & OLADIPS

(INTRO)

Ibile! Omo Iya Aje, Oladips
Lord Of Ajasa, omi ata
Alaga is kidi-diDi, Lord Of Ajasa is jigi-jigi
Lord Of Ajasa; ahn ahnn

(CHORUS- Oladips)

Gbedu eleyi de ma n jo cable- o de ma n jo cable
E ba mi wa awon omo t’o ye-cable: omo t’o ye-cable
Ajasa ti wa online, ‘vailable- o ti wa aVailable
Kuro lona, Alaga fe webo; ehh

Emi o fe awon Pantiewa- Pantiewa, eh
Aburo, ba mi p’Aunty e wa; ehehh
Emi o fe awon Pantiewa- Pantiewa, yeh
Aburo, ba mi p’Aunty e wa; ba mi p’Aunty e wa; ehh

(Lord Of Ajasa- VERSE 1)

Ahh; Omo Ope, ko ni s’ewu
Jaye lo, Oluwa ti segun; oti wa n’le t’e ba fe mu
Ba mi gbenu si no be atenu
Oju po lori ise yen
Iwo na wa lori ise yen?
A jo ni lole tori ise yen
E je k’a ma wo eni t’o ma gori ise yen
T’o ba ti dele, oya e jupa
Ile Ijo yi, awa la ma tuka
This small body is thou full of oja
See noboDy cos o ti fo si mi l’ara

(CHORUS- Oladips)

Gbedu eleyi de ma n jo cable- o de ma n jo cable
E ba mi wa awon omo t’o ye-cable: oMo t’o ye-cable
Ajasa ti wa online, ‘vailable- o ti wa available
Kuro lona, Alaga fe webo; ehh

Emi o fe awOn Pantiewa- Pantiewa, eh
Aburo, ba mi p’Aunty e wa; ehehh
Emi o fe awon Pantiewa- Pantiewa, yeh
{Ibile}
Aburo, ba mi p’Aunty e wa; ba mi p’Aunty e wa; ehh

(Reminisce- VERSE 2)

Bi ibe ba gbe, a lo saliva
Ibile; yo si won bi ti Malaika
Lori micrOphone lodo Ajasa
Erikina lawa oh, pasa pasa
Oya bere to k’o le feel the story
Egun tuntun woLe de, Giringory
T’o ba fe joja, so fun p’o need poli
T’o ba lo kere, bo sokoto je o ri
Iko ni ma fi ye tori opolo po
Mi o n r’irin idoti, no roforofo
Wo awon ore l’okan t’on soko soko
Eru wa n’le, mo ni Dollar loso losO

(CHORUS- Oladips)

Gbedu eleyi de ma n jo cable- o de ma n jo cable
E ba mi wa awon oMo t’o ye-cable: omo t’o ye-cable
Ajasa ti wa online, ‘vailable- o ti wa available
Kuro lona, Alaga fe webo; ehh

Emi o fe awon PantiEwa- Pantiewa, eh
Aburo, ba mi p’Aunty e wa; ehehh
Emi o fe awon Pantiewa- Pantiewa, yeh
Aburo, ba mi p’AunTy e wa; ba mi p’Aunty e wa; ehh

(OUTRO)

O de ma n jo cable; omo t’o ye-cable
O ti wa available; ehh
O de ma n jo cable; omo t’o ye-cable
O ti wa availAble; ehh

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here